Ìràpadà Ìlépa-ỌkànÀpẹrẹ

Gbólóhùn òrò kan wa ni àdúrà tó ń fínni lọkàn bálè tí a sábà máa ń gbà ní ìpàdé ẹlẹsẹ méjìlá tó ń bè Olórun láti ràn wá lówó láti gbà “ ìpónjù ní ìpà ọnà sí àlàáfíà; mímú, ayé èsè yìí gégé bí Jésù ṣee mú, kìí ṣe bí mo sé féé”.
Gbólóhùn yen máa dúró yàtò simi nígbà gbogbo nítorí òpò okun ní mo lọ ní ìgbìyànjú láti ṣàtúnṣe àti darí àwọn ipò àti àwọn ènìyàn tó ń mbè láyíkà mí kí mbá lè ṣẹda ìgbé ayé ní ònà tí mo fẹẹ... ìlàkáká láti mú àlà mi wá sáyé. Ní kédéré èyí kò ṣiṣẹ́.
Léyìn ìpínyà èmi àti ọkọ mi, Mo pàdánù ilè mi, iyì mi párun, àti pé mo nímòlárà pé, òkòòkan, gbogbo àwọn àwòn ààbò tí mo gbè kálẹ̀ fún ará mi, àti ìgbé ayé tí Mo ń gbìyànjú láti kó lọ tú palè pátápátá. Ayé kò rí bí Mo ṣe féé.
Ní àkókó kan, Mo rí ara mi pé ńmo sukún lórí è gidi àti mo sí sukún sí Olórun, àbájáde é kò rí bí mo ṣe ró pé o máa jé ”. Olórun fetí sílẹ. Àti pé nígbà náà, O sòrò sínú ọkàn mi.
Mo tí gbà ọ là.
Òmùgò nínú gbólóhùn yìí fèèrè múní rérìn. Kòsí nńkan kan nípa ohun tí mo ń la kọja tó jó mo ìràni padà kódà o jìnnà sí í.
Harmony, Mo gbà ọ là lówó ẹyà àlà rè... Mo máa rà àlà náà padà.
Ìlérí yìí, pé Olórun yòó dá àlà náà padà, pé Òun yòó dá ẹbí mi padà sí mi, fúnmi nírètí pé àkókò ti mo wá nínú rẹ yìí kò ní pé.
Mo mò Olórun láti jé Olúrapadà. Àkókò, O rà ìtàn ìrora àti lilọ nílòkulò mi padà àti pé O.ń lọ láti kàn sí àwọn mìíràn nípase Wúrà. Today, òpò ọdún léyìn ìpínyà, Mo lè sò fún yín pé O tí rà àlà mi fún ìdápadà ebí mi padà.Ni oṣù kẹta tí ọdún 2014, Mọ se ìgbéyàwó pèlú arákùnrin kan tó jé àgbàyanu, olólúfé, bàbá ìkejì sí omo mi obìnrin mí to réwà! Ní oṣù kínní ọdún 2018, a ní ọmọ ìkókó ọkùnrin tó rẹwà tó tí mú ìdùnnú púpò sínún ilè wa.
Mo fẹràn ìtàn Jóséfū, nítorí o jé àpẹẹrẹ àlála tó gbékélè Olórun, kódà nígbà tí o da bí pé gbogbo àlà rè tí fó yàngà. Àwọn mọlebi rè dà a, won fí sílè, mú lérú, won fi sẹ́wọ̀n, àti gbàgbé rẹ. Ni gbogbo èyí, Olórun wá pèlú Jóséfū. Nígbèyìn, òtítọ rẹ nínú Olórun jé kí o borí wa àwọn ipò àti gbà ẹbí rè là àti gbogbo Égíptì lówó èèrùn. Olórun lọ òkòòkan ìgbé ayé àti ìtàn Jóséfù fún dára dára! Ọlórun dà àlà náà padà.
O ṣe mi ní kàyéfì pé ǹjé a tí é dàn Jóséfù wó rí júwò àlà náà sílè? Kàkà béè, O jé onígbàgbọ jákèjádo gbogbo àkókò yìi àti àwọn ipò ìlàkáká, o jé kí Olórun lo o, o sí múra sí àlà lílà. A gbà orílè-èdè kan là nítorí òdodo Rẹ̀.
Mi o mò ohun tí o ń la kọjá. Mí o mò irú àwọn àdánwò àti àtakò àwọn àlá Olórun fún ayé è tí fara da.Àmó mo mò èyí—Olúrapadà ní Olórun. Olódodo ni Òun. Bí o ń se lalá, túbò máa gbékélè, túbò máa forítì i…
Olórun máa ra ala é pàdà.
Ìwé pélébé láti Harmony:
Mo nírètí pé o gbádùn ìfọkànsín yìí! Máa fé láti máa tèsíwájú láti fún ọ nísíri láti máa gbé ni òmìnira, lálà nlá, àti máa ṣe dáadáa! Mo pè o lati yè búlọ́ọ̀gì mi wó ni www.HarmonyGrillo.com. Láti kẹ́kọ̀ọ́ púpò mo nípa Wúrà, o lè ṣayewò www.iamatreasure.com.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Kíni a lè ṣe nígbà tí àwọn ìlépa wa bá dàbí èyí tó jìnà réré tàbí bíi ìgbà tí a kò bá lè bá a láíláí? Lẹ́yìn tí mo borí ìlòkulò àti ìbanilọ́kànjẹ́, pẹ̀lú ẹ̀dùn ọkàn ti ìkọ̀sílẹ̀, mo ti dojúkọ ìbéèrè yìí lẹ́ẹ̀kànsi. Bóyá ò ń ní ìpèníjà ti àjálù tàbí ọ̀fọ̀, tàbí ìbànújẹ́ ti àkókò ìdádúró, ìlépa Ọlọ́run fún ìgbésí-ayé rẹ ṣì wà láàyè! Ọ̀rẹ́, àkókò tó láti lá àlá lẹ́ẹ̀kansi.
More