Ìràpadà Ìlépa-ỌkànÀpẹrẹ

Ìgbàgbọ́ kò mú ní àjẹsára sí àwọn ìṣòro ayé. Àwọn ìgbà kan wà tí a máa sọ iṣẹ nu, àwọn ọkàn máa ní ìrora, tàbí àwọn tí a féràn máa kúrò nígbà tí kò i tí di ìgbà wọn.
Àwọn àkókò mìíràn tún wà nígbà tí a máa mú wa dúró (dúró àti dúró) fún àwọn àlà wa láti wá símúse. àlà fún ọmọde, ọkọ tàbí aya, tàbí ìdápadàbosipo ìbáṣepọ̀. Fún olólúfé wa láti borí àìlera tàbí baraku ìfé kufèé. Fún ìsinmi níbi isé ìgbé ayé wa. Ọkan wa o má ní ìrora pèlú ìyánhànhà fún awọn ohun tí a kò ní lówólọwó. Nígbà mìíràn, ìrora fún ìrètí wa tó jẹ pé dín kù àti pé kódà a lè júwò àlà náà sílè, torí náà kò pánílara púpò rárá.
Olórun bíkíta nípa àwọn àlà wa. Ní tòótọ, O fi “àwon àlà Olórun” sínú ọkàn ọkánkán wa. Àmó, tí mo bá fé àlà náà jù Olórun lo, Afúnni lálà, Mo so àlà náà dí òrìsà.
Láti ìgbà tí mo tí ní omo odún méjì, Mo fé jé òṣèré tó gbajúmọ̀. Bí ọmọdé, Mo lo wákàtí níwájú dígí ń ṣebi àwọn èèyàn inú ìtàn. Àbùkù àti ìlòkúlo dojú ti me gbogbo àlà mi, ìyen náà pèlú. Nígbà tí mo bá fé sí ní rìn pèlú Jésù, Mo pinnú láti pinnú láti lépa isé òṣèré lékán si.
Mo ń máa booking isé Mo máa ṣí ní àkókò tó dára ní kíkó isé ìgbé ayé àmó, láìpé Mo rí I pé Ọlọ́run ní àlà tó yàtò fún ayé mi jù èyí tí ń ko aare tẹle lo.
Tí mo bá jé olóòótọ, ìfé mi láti jé òṣèré wá láti jẹ díè nípa fífẹ láti ní ìmólárá of ìjépàtàkì. Olórun fé jé kí rí ìyi mi nínú Òun, kìí ṣe láti inú ìfẹ̀gbẹ́kẹ̀gbẹ́ àti ìdánimọ̀ tí mo lè rí gbà gégé bí òṣèré. Mo tún bèrè sí ní lóyè to pé O fé lo ìrora láti ìgbà past mi láti mú ìrètí àti òmìnira fún àwọn mìíràn.
Mo pinnú láti telé Àlà Olórun fún ayé mi àti ní 2003, Mo dá Wúrà sílè, ègbé délé-dóko àti àtìlẹ́yìn sí àwọn tó jìyà lilọ ibàlopò àti fàyàwọ́. Mo ń máa rí, I get to see àwọn ìpa bi àbájáde ìpinnu mi láti tẹlé àlà Olórun fún ayé mi!. Tí mo bá tí tèsíwájú láti hold on to àlà òṣèré mi, tàbí búburú jù bẹẹ lo, kí o dí òrìṣà nínú ayé ji, Máa tí kùnà àlà tí Ọlórun ni lọkàn fún mi!
Olórun bíkíta nípa wa, àti pé O bíkíta nípa àwọn àlà wa. O bíkíta tó tó jé pé O ń ṣetán láti darí wa kúrò ní ohun tí a rò pé a fé, kí O bá lè darí wa sínú ohun ti Omní fún wa.
Àlà Olórun mbè fún ayé e. O lè jé ohun tí o tin rìn sún mo, tàbí ohun tí ontie lérò rárá. Mo gbàgbó pé bí o ń se mú àwọn ètò àti àlà rè pèlú owó sísísílè, àti gbékélè É pẹlú ìlànà náà, O máa darí è sí ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ohun tí O ní fún ọ ni ìtọjú.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Kíni a lè ṣe nígbà tí àwọn ìlépa wa bá dàbí èyí tó jìnà réré tàbí bíi ìgbà tí a kò bá lè bá a láíláí? Lẹ́yìn tí mo borí ìlòkulò àti ìbanilọ́kànjẹ́, pẹ̀lú ẹ̀dùn ọkàn ti ìkọ̀sílẹ̀, mo ti dojúkọ ìbéèrè yìí lẹ́ẹ̀kànsi. Bóyá ò ń ní ìpèníjà ti àjálù tàbí ọ̀fọ̀, tàbí ìbànújẹ́ ti àkókò ìdádúró, ìlépa Ọlọ́run fún ìgbésí-ayé rẹ ṣì wà láàyè! Ọ̀rẹ́, àkókò tó láti lá àlá lẹ́ẹ̀kansi.
More