Ìràpadà Ìlépa-ỌkànÀpẹrẹ

Dreams Redeemed

Ọjọ́ 4 nínú 7

Ibanuje ati irora ni ọna ti o ma nfi nse asekun si adanwo. Wọn tunbo si wa sile lati f'aragba awọn aisedede wa. Yala ni ti iyarasoto, ajeju ounje, isagbere, imoti para, sísá fun irora a máà mu wa ni ifasehin. Aa ma so funra wa pe arayá to ju bayi lo tósi wa.

Ti a ba wa nnu inira, a ma n yara lati rubọ ala naa fun ohun ti o jẹ fun igba diẹ. Itura naa ti iwa asise wa ma nmu wa ò kinpe, ko si ni ijinle.

Asehan kan wa ni Opera olokiki, LA Boehme eyiti awon okunrin meji kan njiya ni igba otutu buburu ni ilu Paris. Okan ninu won je onkowe, ti o ti lo opolopo wakati lori ise kan pato. Otutu yi buru to be ti ko le pa okan po si iwe kiko re mo.

Laini owo ati ra edu tabi igi lati fi dana, ni akoko ainireti kan, onkowe yii da gbogbo iwe ti o ti nko bo sinu ina. Ni seju aaya gbogbo iwe na pelu ohun ti o ko si jo di eeru.

Onkowe yi rubo ala re, ohun gbogbo to ti sise fun, fun idera ranpe. O juwo re nu.

A rí apẹrẹ kanna ninu itan Esau ti o wa ninu iwe Genesisi. Ninu irera ati ébí o dari si ile to kun fun oorun obe asaro gbigbona. Ni igbokansoke fun oun amarale, Esau jowo ogún ibi re, gbogbo anfani, ase ati ogun ti o je ti akobi fun obe adaro gbona. O rubo ojo ola re fun igbadun mo-yo.

E tétisi, o yé mi.

Mo nni adanwo lati jẹ awọn ikunsinu mi nigbati okan mi ba gbogbe (Opo igba ni mo ma njuwo re nu). Lehin ikora eni sile, idawa danmiwo lati ba eni ti o ye jade. Modupe wipe adanwo na ko bori mi bi o tile je wipe o wa nibe.

Nigbati mo npadanu ile mi ni tente ijakule owo ina mi, alabagbele kan se ifilo ise ti won ma san milionu owo nibise ountaja apo-ogun kan. Ise na womiloju sugbon iba se okunfa fifi ise Treasure si eyin aro. Itunu igba die ti agbara iduroṣinṣin esuna owo ti o tobi julọ ko to lati fi ipe ti Oluwa pe mi sile.

Nigba miran Ala Ọlọrun nfé ki a rubo. Abalo ababo re Ọlọrun nfiyesi iwa wa ju iderun wa lo.

A le je ki awon isoro kowa ni iwa rere abi ki o bii wo. A le rubo ala wa fun ohun itura ranpe, abi ki a se aforiti ki aforiti wà wá ràn iwa rere lowo ki a wa dagbasoke ninu ise rere.

E ma fi ala yin sile fun ohun ti o wa fun igba die. Mase je ki irora abi ijakule mu e fi igbadun ranpe padanu ala re. Ma gba o, ohun ti o wa nile lagbara o.

Ominira wa lopin iwa isotitọ rẹ. Fun ati iwo ati fun gbogbo eniyan ti gbigbe igbe aye ti Oluwa yan fun e ni kikun yo je awo kose fun.

Ọjọ́ 3Ọjọ́ 5

Nípa Ìpèsè yìí

Dreams Redeemed

Kíni a lè ṣe nígbà tí àwọn ìlépa wa bá dàbí èyí tó jìnà réré tàbí bíi ìgbà tí a kò bá lè bá a láíláí? Lẹ́yìn tí mo borí ìlòkulò àti ìbanilọ́kànjẹ́, pẹ̀lú ẹ̀dùn ọkàn ti ìkọ̀sílẹ̀, mo ti dojúkọ ìbéèrè yìí lẹ́ẹ̀kànsi. Bóyá ò ń ní ìpèníjà ti àjálù tàbí ọ̀fọ̀, tàbí ìbànújẹ́ ti àkókò ìdádúró, ìlépa Ọlọ́run fún ìgbésí-ayé rẹ ṣì wà láàyè! Ọ̀rẹ́, àkókò tó láti lá àlá lẹ́ẹ̀kansi.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Harmony Grillo (I Am A Treasure) fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé síwájú sí, jọ̀wọ́ lọ sí: http://harmonygrillo.com