Ìràpadà Ìlépa-ỌkànÀpẹrẹ

Ọjó àwọn ìyá mi àkókọ́ - Ojó tí mo gbèró pé o máa kún fún àwọn òdòdó àwọn èrò ìmólárá toń tú jáde. Kàkà béè, mo rí ará mi tí mò fetí gbó ìjéwò tó máa fópin sí ìgbéyàwó mi. Erù bámi àti edùn ọkàn sí bámi, Mi ko sí nípò láti ṣe òbí fún ọmọ ìkókó mi obìnrin ní ọjọ́ tí mo bíi sáyé. Àwon òré mi òwón se inú réré tóo láti mú sọdò fún aṣálẹ náà.
Nígbà tí mo lọ mú u lójó kejì, Mo jókòó àgbàrá omije lórí kápéètì pálò won, ń sukún. “Èmi ni ìyàwó. A jọ jé èjé. O yé kí a jo tò àwọn ọmọ wa papò àti ní ọmọ àti àwọn ọmọmo papò. Awa lọ máa fópin sí ìpínyà ìgbéyàwó nínú ẹbí kánkán wa. O yé kí a dárúgbó àpapọ.”
O tétí sí mí tàánútàánú kí o tó sò àkíyèsí rè. “Harmony, o dàbí pé o tí yà àwòrán bí o fé kí ayé rè se rí. Mo mò pé o lẹ, àmó . Àkókò lè tí tó láti jòwó àwòrán àti gbékélè Olórun láti yà àwòrán títún mìíràn”.
Òótọ́ ọ̀rọ̀ ló sì sọ”Mi o sukún lórí ìgbé ayé tí Mo mò nìkan, àmó èyí tí mo gbèrò ń yà àwòrán bí ayé wa máa má dàbí. A ti yà àwòrán ìgbéyàwó wa sórí, àwọn ọmọ, isé ìgbé ayé, àwọn ìbáṣepọ̀ òré, àti kódà nígbà mìíràn àtẹ ojó ìṣèlè fún gbogbo àwọn nńkan wónyìí.
Ìran jé ohun tó dára, àmó kí ló ṣẹlẹ nígbà tí àwọn ìlépa ọkàn wa àti àwọn ohun tán rètí fó yángá, ìjàkulè ayé? Nípa ikú eni tá féràn, ìtúpalẹ̀ ìgbéyàwó tó tú ká, tàbí ìpàdánù isé ìgbé ayé eni? Báwo ni a se ń hùwà? Se a máa bínú sí Olórun pèlú dáhùn ní ìkòrò? Se a máa jé èjé we láti má ní ìlépa ọkàn mó rárá, nítorí o tí pojú fún wa láti ní ìrètí? Tàbí, àbí se a fé láti sí owó wa sílè kí a jòwó àwòrán ayé rẹ fún Un.
Emí náà ti yà àwòrán bí ayé mi máa se rí, àmó Mo tí pé àwòrán náà lè má wà ṣedéédéé pèlú àwòrán ìgbèyìn tí Olórun ń ya fún mi.
Ìròkurò lè dí òrìṣà. Èyí máa ṣẹlẹ̀ nígbà tí a bá fi igbékélè wa sórí àwòrán tí a gbè nínú ọkàn wa fún ara wa. O lè jé ohun tó rọrùn láti fi igbékélè wa lórí nkán tí a lè rí àti darí, jù kí a fí igbékélè wa sínú Olórun tí a kò lè rí àti darí.
Ìbáṣepọ̀ òtítọ́ àti àjọṣe tímótímó lè báni lérù. Ìwòsàn lè dérū báni. Àwọn ohun wónyìí fé igbékélè ìgboyà láti rìn pèlú Olórun lórí àwọn ìpà tí a kò mò rí nípa ọnà tí kò mọ wa lára. Àmó Olórun, Olórun wá fé mú wa rìn ìrìn àjò yìí. O máa mú àwọn ibi tó ṣe gbágungbàgun dì didán àti mú ìmọ̀lè wá sí bi ti kò sí.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Kíni a lè ṣe nígbà tí àwọn ìlépa wa bá dàbí èyí tó jìnà réré tàbí bíi ìgbà tí a kò bá lè bá a láíláí? Lẹ́yìn tí mo borí ìlòkulò àti ìbanilọ́kànjẹ́, pẹ̀lú ẹ̀dùn ọkàn ti ìkọ̀sílẹ̀, mo ti dojúkọ ìbéèrè yìí lẹ́ẹ̀kànsi. Bóyá ò ń ní ìpèníjà ti àjálù tàbí ọ̀fọ̀, tàbí ìbànújẹ́ ti àkókò ìdádúró, ìlépa Ọlọ́run fún ìgbésí-ayé rẹ ṣì wà láàyè! Ọ̀rẹ́, àkókò tó láti lá àlá lẹ́ẹ̀kansi.
More