YouVersion Logo
Search Icon

Saamu 91:2

Saamu 91:2 BMYO

Èmi yóò sọ nípa ti OLúWA pé, “Òun ni ààbò àti odi mi, Ọlọ́run mi, ẹni tí èmi gbẹ́kẹ̀lé”.

Free Reading Plans and Devotionals related to Saamu 91:2