Saamu 116:1-2
Saamu 116:1-2 YCB
Èmi fẹ́ràn OLúWA, nítorí ó gbọ́ ohùn mi; ó gbọ́ ẹkún mi fún àánú. Nítorí ó yí etí rẹ̀ padà sí mi, èmi yóò máa pè é ni wọ́n ìgbà tí mo wà láààyè.