YouVersion Logo
Search Icon

Matiu 5:6-7

Matiu 5:6-7 YCB

Alábùkún fún ni àwọn tí ebi ń pa tí òǹgbẹ ń gbẹ́ nítorí òdodo, nítorí wọn yóò yó. Alábùkún fún ni àwọn aláàánú, nítorí wọn yóò rí àánú gbà.

Free Reading Plans and Devotionals related to Matiu 5:6-7