YouVersion Logo
Search Icon

ORIN DAFIDI 142:7

ORIN DAFIDI 142:7 YCE

Yọ mí kúrò ninu ìhámọ́, kí n lè yin orúkọ rẹ lógo. Àwọn olódodo yóo yí mi ká, nítorí ọpọlọpọ oore tí o óo ṣe fún mi.

Free Reading Plans and Devotionals related to ORIN DAFIDI 142:7