YouVersion Logo
Search Icon

ÌWÉ ÒWE 3:9-10

ÌWÉ ÒWE 3:9-10 YCE

Fi ohun ìní rẹ bọ̀wọ̀ fún OLUWA pẹlu gbogbo àkọ́so oko rẹ. Nígbà náà ni àká rẹ yóo kún bámúbámú, ìkòkò waini rẹ yóo sì kún àkúnya.

Free Reading Plans and Devotionals related to ÌWÉ ÒWE 3:9-10