JOṢUA 2:8-9
JOṢUA 2:8-9 YCE
Kí àwọn amí meji náà tó sùn, Rahabu gun òrùlé lọ bá wọn, ó ní, “Mo mọ̀ pé OLUWA ti fi ilẹ̀ yìí lé e yín lọ́wọ́, jìnnìjìnnì yín ti bò wá, ẹ̀rù yín sì ti ń ba gbogbo àwọn tí wọn ń gbé ilẹ̀ yìí.