YouVersion Logo
Search Icon

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 2:21

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 2:21 YCE

Nítorí pé nígbà mìíràn ẹni tí ó ti ṣiṣẹ́ pẹlu ọgbọ́n, ìmọ̀ ati òye yóo fi gbogbo rẹ̀ sílẹ̀ fún ẹni tí kò ṣe làálàá fún wọn. Asán ni èyí pẹlu, nǹkan burúkú sì ni.

Free Reading Plans and Devotionals related to ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 2:21