1
ORIN DAFIDI 47:1
Yoruba Bible
YCE
Ẹ pàtẹ́wọ́, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè; ẹ kọ orin ayọ̀, ẹ hó sí Ọlọrun.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 47:1
2
ORIN DAFIDI 47:2
Nítorí pé ẹ̀rù jẹ̀jẹ̀ ni OLUWA, Ọ̀gá Ògo, Ọba ńlá lórí gbogbo ayé.
Explore ORIN DAFIDI 47:2
3
ORIN DAFIDI 47:7
Nítorí Ọlọrun ni Ọba gbogbo ayé; Ẹ fi gbogbo ohun èlò ìkọrin kọ orin ìyìn!
Explore ORIN DAFIDI 47:7