Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

Advent: Christ Is Coming!

Ọjọ́ 9 nínú 91

TAN IMỌLẸ NÁÀ

A n'reti Mesaya!
Ṣé o ṣọra láti gbé gẹgẹ bí ẹnití o níye lórí pèlú Ọlọrun.

KA AWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ
Majẹmu òfin Ọlọrun
Deuteronomi 4:1-13

DAHUN PẸLU ÌJỌSÌN

Ṣe ìjọsìn pẹlu ayé rẹ
Ọlọrun fún àwọn ọmọ Israẹli ní òfin, àwọn òfin mẹwàá. Kíni ìdí tí Ọlọrun ṣe ṣe bẹẹ? (Ofiri, ka Róòmù 3:20 ati Galatia 3:23-26.) Njẹ iwọ dupe fún àwọn òfin tí o pa ọ mọ́ kúrò nínú ewu?

Ṣe ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ Bíbélì lati júbà, jewo, yin, ati dupẹ lọwọ Ọlọrun.

Ṣe ìjọsìn pẹlu orin
Kọ orin "Wá Jésù tí a ti n'reti "
Ọjọ́ 8Ọjọ́ 10

Nípa Ìpèsè yìí

Advent: Christ Is Coming!

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.

More

A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org