Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

Advent: Christ Is Coming!

Ọjọ́ 4 nínú 91

TAN IMỌLẸ NÁÀ

A n'reti Mesaya!
Ọnà wo ni iwọ nrin pẹlu Ọlọrun nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ nínú Jésù?

KA AWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ
Àmì Majẹmu Ọlọrun pẹlu Noah
Jenesisi 9: 8-17

DAHUN PẸLU ÌJỌSÌN

Ṣe ìjọsìn pẹlu ayé rẹ

Òsùmàrè yíká itẹ Ọlọ́run (wo ìwé Ìfihàn 4:3). Kíni iwọ nro tí o bá rí Òsùmàrè? Ṣé iwọ má nyìn Ọlọrun fún ìtọjú Majẹmu rẹ̀?

Ṣe ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ Bíbélì lati júbà, jewo, yin, ki ọ sí dupẹ lọwọ Ọlọrun.

Ṣe ìjọsìn pẹlu orin
Kọ orin "Angẹli láti àwọn ògo ti ologo"

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 3Ọjọ́ 5

Nípa Ìpèsè yìí

Advent: Christ Is Coming!

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.

More

A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org