Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

Advent: Christ Is Coming!

Ọjọ́ 3 nínú 91

TAN IMỌLẸ NÁÀ

A n'reti Mesaya!
Ṣe iwọ gbé ayé idupe sí Jésù loni?

KA AWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ
Majẹmu Ọlọrun sí Noah
Jenesisi 6-7

DAHUN PẸLU ÌJỌSÌN

Ṣe ìjọsìn pẹlu ayé rẹ
Ọlọrun pèsè ọnà fún Noah àti ìdílé rẹ̀ láti koyo nínú iṣan omi, ọkọ na. Ọkọ wo ni Olorun pèsè fún ìgbàlà rẹ (wo Rómù 5:8-9)? Njẹ iwọ gbẹkẹle e? Noah ba Ọlọrun rìn. Njẹ iwọ nbà Ọlọrun rìn tàbí ayé? Sọ nípa àwọn ìgbà tí o bá Ọlọrun rìn àti ìgbà tí o ní ijakadi pẹlu ohun ayé. Ṣé Ọlọrun jẹ́ olotitọ sí ọ.

Ṣe ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ Bíbélì lati júbà, jewo, yin, ati dupẹ lọwọ Ọlọrun.

Ṣe ìjọsìn pẹlu orin
Kọ orin "Ẹwà ẹyin oloootitọ"
Ọjọ́ 2Ọjọ́ 4

Nípa Ìpèsè yìí

Advent: Christ Is Coming!

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.

More

A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org