Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

Advent: Christ Is Coming!

Ọjọ́ 7 nínú 91

TAN IMỌLẸ NÁÀ

A n'reti Mesaya!

KA AWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ
Majẹmu ayérayé fún Abrahamu fún gbogbo ìran
Orin Dáfídì 105:1-10

DAHUN PẸLU ÌJỌSÌN

Ṣe ìjọsìn pẹlu ayé rẹ
A ti gba ìbùkún Majẹmu Ọlọrun pẹ̀lú Abrahamu (wo Galatia 3:14). Ka Orin Dáfídì 105-1 lẹẹkan sí. Kí olúkúlùkù sọ ohun tí oni ká se. Njẹ́ a ngbe ní ònà yìí?

Ṣe ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ Bíbélì lati júbà, jewo, yin in, ki ọ sí dupẹ lọwọ Ọlọrun.

Ṣe ìjọsìn pẹlu orin
Kọ orin "Ayọ̀ sí ayé"
Ọjọ́ 6Ọjọ́ 8

Nípa Ìpèsè yìí

Advent: Christ Is Coming!

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.

More

A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org