Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

TAN IMỌLẸ NÁÀ
A n'reti Mesaya!
KA AWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ
Majẹmu pẹ̀lú Abrahamu, Isọtẹlẹ ti Mesaya.
Jenesisi 12:1-3 ati 26:1-5
DAHUN PẸLU ÌJỌSÌN
Ṣe ìjọsìn pẹlu ayé rẹ
A bùkún fún gbogbo àwon ìdílé ní orí ilẹ̀ ayé nipasẹ Abrahamu. Èyí jẹ́ bẹẹ nítorí Jésù, ẹnití o wá láti àlà Abrahamu. Ọna wo ni Jésù ṣe bùkún rẹ? Abrahamu gbagbo osi se ìgbọràn ṣí Ọlọrun. Njẹ́ iwọ gbà Ọlọrun gbọ, tí o sí gbọràn síi?
Ṣe ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ Bíbélì lati júbà, jewo, yin, ati dupẹ lọwọ Ọlọrun.
Ṣe ìjọsìn pẹlu orin
Kọ orin "Yin Ọlọrun, ọdọ ẹni tí gbogbo ibukun ti sàn wá "

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.
More
A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org