Ìgbé Àyè Kristeni, Ìgbé Ayé Ìrúbọ Àti iṣẹ ÌsìnÀpẹrẹ

Bóri Ibi Pẹlu Rere
Nipa, t'ara Ogba ọpọlọpọ láti yọnda ẹtọ wà láti gbá ẹsan fún àrà wà pápá nígbà to hàn gbángba pé ẹlomi ṣe lòdì sí wá tabi rẹ wá jẹ ṣugbọn bí onigbagbọ nínú Kristi ìrúbọ to nilo lati ṣe ni.
Ipe na niyii, jẹki Ọlọrun gbẹsan fún ọ "iṣẹ ẹtọ Ọlọrun ni lati gbẹsan" gbẹkẹle pé Yíò ṣe. Asọ fún wa níbí k a "fún ọtá wà ni ounjẹ àti omí mú" Vs. 20, ṣe eléyìí owá jẹ ìgbésẹ to pọju? Olè bèèrè.
Kristi Jésù fún wa ni itọni¹ kàn na ṣugbọn ṣe eleyii túmọ sí pé kí a ma gbé ìgbésẹ igbẹ́jọ fún ìdájọ́ to bá ṣe kókó? Rárá! Sugbọn ma ṣe fi ọwọ́ ará rẹ gbẹsan ti obá tilẹ ni anfaani na.
Àbájáde rẹ yóò jasi iṣelodi nítorí nínú ìpinu lati ṣe ìdájọ fún àrà rẹ wà fi ayè fún ẹran àrà àti ìṣẹlẹ ìbí, máṣe eleyii. Yọnda ipohungbẹ fún ẹsan lati ṣe ìdájọ pẹlu ọ̀iwọ́ rẹ.
Kíkà síwájú sí i: Mátíù 5:38-40
Aura: OLUWA, mo yọnda lóni gbogbo ipohungbẹ nínú mi lati fẹ ṣe ìdájọ pẹlu ọ̀wọ́ ará mí fún àìdá ti ẹlomii ṣe sí mi.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Igbe Ayé Kristeni kii ṣe ìgbé Ayé irọrun, ọrọ àti itẹlọrun ní gbogbo ìgbà ṣugbọn ojẹ ìgbé Ayé Ìrúbọ ati ìsìn. Jésù wá sí ayé láti wá fi àpẹẹrẹ náà hàn fún wa láti ri. Jésù wá, o gbè ìgbé Ayé isẹrà ẹni, aimọtàrà ẹni nikan, iyasọtọ, iwọntunwọnsi ati ìrúbọ titi ti O fi kù fún ìràpadà wá. Ìdí yii ni àfi ni àkọsílẹ̀ rẹ ninú awọn ìwé ìhìnrere.
More
A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL