Ìgbé Àyè Kristeni, Ìgbé Ayé Ìrúbọ Àti iṣẹ ÌsìnÀpẹrẹ

Isopọ Pẹlú Ará Kristi
Oṣe pataki kiõ mọ pe Ọlọrun pé Ọ lati faramọ ẹyà ti a mọ gẹgẹbi "Ará" Kristi. O lè yà ará rẹ si ọtọ bẹni o lè dáwà sìn Ọlọrun.
Ni ìbámu pèlú èyí ati fún ọ lati ọrun wá, òré ọfẹ ẹbun ati ipá ṣugbọn èyi o wipe ọtí gà jù gbogbo ẹlòmíràn lọ, níbẹ kiyesii ìkìlọ nà; máṣe rò ara rẹ̀ jù bi o ti yẹ ni erò lọ; ṣugbọn ki o ṣe ìdájọ ará rẹ pẹlú ìrẹlẹ ọkan. Vs. 3
O ṣe kókó kí o mọ nipa itọni Ọlọrun; ẹbun, Aye ati iṣẹ rẹ nínú ará Kristi (ìjọ ni àgbáyé) ṣugbọn èyí yíó bẹrẹ nínú isé ati iwà rẹ̀ ninú ìjọ àgbègbè ibi tí ìrìn àjò ìgbàgbọ rẹ ti bẹ̀rẹ̀. Kiyesii pé ìjọ agbègbè rẹ àti ìjọ ni àgbáyé ọkan ni wọn jẹ́, ni idapọ pẹlu Kristi, Ẹmí Mimo ati Bibeli.
Ṣíṣe eleyii to ṣáájú a ran Ọ lọwọ láti mú ìdàgbàsókè nínú ẹmí ati iṣẹ Ìsìn rẹ ṣẹ ju gbogbo ẹ lọ, o pari ìpinu ati ètò Ọlọrun fún ọ.
Kíkà síwájú sí i: Éfésù 4:10-14, 1 Kọ́ríńtì 12:12-19
Adura: OLÙWÀ, dari mi lati lè mọ ati lati lè ri àye mi àti iṣẹ ti o yan fun mi ni ará Kristi.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Igbe Ayé Kristeni kii ṣe ìgbé Ayé irọrun, ọrọ àti itẹlọrun ní gbogbo ìgbà ṣugbọn ojẹ ìgbé Ayé Ìrúbọ ati ìsìn. Jésù wá sí ayé láti wá fi àpẹẹrẹ náà hàn fún wa láti ri. Jésù wá, o gbè ìgbé Ayé isẹrà ẹni, aimọtàrà ẹni nikan, iyasọtọ, iwọntunwọnsi ati ìrúbọ titi ti O fi kù fún ìràpadà wá. Ìdí yii ni àfi ni àkọsílẹ̀ rẹ ninú awọn ìwé ìhìnrere.
More
A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL