YouVersion Logo
Search Icon

O. Daf 47:1-6

O. Daf 47:1-6 YBCV

ẸNYIN enia, gbogbo ẹ ṣapẹ; ẹ fi ohùn ayọ̀ hó ihó iṣẹgun si Ọlọrun. Nitori Oluwa Ọga-ogo li ẹ̀ru; on li ọba nla lori ilẹ-aiye gbogbo. On ni yio ṣẹ́ awọn enia labẹ wa, ati awọn orilẹ-ède li atẹlẹsẹ wa. On ni yio yàn ilẹ-ini wa fun wa, ọlá Jakobu, ẹniti o fẹ. Ọlọrun gòke lọ ti on ti ariwo, Oluwa, ti on ti iró ipè. Ẹ kọrin iyìn si Ọlọrun, ẹ kọrin iyìn: ẹ kọrin iyìn si Ọba wa, ẹ kọrin iyìn.

Related Videos

Verse Images for O. Daf 47:1-6

O. Daf 47:1-6 - ẸNYIN enia, gbogbo ẹ ṣapẹ; ẹ fi ohùn ayọ̀ hó ihó iṣẹgun si Ọlọrun.
Nitori Oluwa Ọga-ogo li ẹ̀ru; on li ọba nla lori ilẹ-aiye gbogbo.
On ni yio ṣẹ́ awọn enia labẹ wa, ati awọn orilẹ-ède li atẹlẹsẹ wa.
On ni yio yàn ilẹ-ini wa fun wa, ọlá Jakobu, ẹniti o fẹ.
Ọlọrun gòke lọ ti on ti ariwo, Oluwa, ti on ti iró ipè.
Ẹ kọrin iyìn si Ọlọrun, ẹ kọrin iyìn: ẹ kọrin iyìn si Ọba wa, ẹ kọrin iyìn.O. Daf 47:1-6 - ẸNYIN enia, gbogbo ẹ ṣapẹ; ẹ fi ohùn ayọ̀ hó ihó iṣẹgun si Ọlọrun.

Ẹ kọrin iyìn si Ọlọrun, ẹ kọrin iyìn: ẹ kọrin iyìn si Ọba wa, ẹ kọrin iyìn.