YouVersion Logo
Search Icon

Òwe 6:20-21

Òwe 6:20-21 BMYO

Ọmọ mi, pa àṣẹ baba rẹ mọ́ má sì ṣe kọ ẹ̀kọ́ ìyá rẹ sílẹ̀. Jẹ́ kí wọn wà nínú ọkàn rẹ láéláé so wọ́n mọ́ ọrùn rẹ.

Free Reading Plans and Devotionals related to Òwe 6:20-21