YouVersion Logo
Search Icon

Òwe 6:16-19

Òwe 6:16-19 BMYO

Àwọn ohun mẹ́fà wà tí OLúWA kórìíra, ohun méje ní ó jẹ́ ìríra sí i, Ojú ìgbéraga, ahọ́n tó ń parọ́ ọwọ́ tí ń ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀, ọkàn tí ń pète ohun búburú, ẹsẹ̀ tí ó yára láti sáré sínú ìwà ìkà, ajẹ́rìí èké tí ń tú irọ́ jáde lẹ́nu àti ènìyàn tí ń dá ìjà sílẹ̀ láàrín àwọn ọmọ ìyá kan.

Verse Image for Òwe 6:16-19

Òwe 6:16-19 - Àwọn ohun mẹ́fà wà tí OLúWA kórìíra,
ohun méje ní ó jẹ́ ìríra sí i,
Ojú ìgbéraga,
ahọ́n tó ń parọ́
ọwọ́ tí ń ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀,
ọkàn tí ń pète ohun búburú,
ẹsẹ̀ tí ó yára láti sáré sínú ìwà ìkà,
ajẹ́rìí èké tí ń tú irọ́ jáde lẹ́nu
àti ènìyàn tí ń dá ìjà sílẹ̀ láàrín àwọn ọmọ ìyá kan.