Gẹnẹsisi 33:1

Gẹnẹsisi 33:1 YCB

Jakọbu sì gbójú sókè, ó sì rí Esau àti irínwó ọkùnrin tí wọ́n ń bọ̀, ó sì pín àwọn ọmọ fún Lea, Rakeli àti àwọn ìránṣẹ́bìnrin méjèèjì.
YCB: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Share