YouVersion Logo
Search Icon

ORIN DAFIDI 65:5

ORIN DAFIDI 65:5 YCE

Iṣẹ́ òdodo tí ó bani lẹ́rù ni o fi dá wa lóhùn, Ọlọrun olùgbàlà wa. Ìwọ ni gbogbo àwọn tí ó wà lórí ilẹ̀ ayé gbẹ́kẹ̀lé, ati àwọn tí wọn wà lórí omi òkun ní ọ̀nà jíjìn réré.

Free Reading Plans and Devotionals related to ORIN DAFIDI 65:5