YouVersion Logo
Search Icon

ORIN DAFIDI 46:1-2

ORIN DAFIDI 46:1-2 YCE

Ọlọrun ni ààbò ati agbára wa, olùrànlọ́wọ́ tí ó wà nítòsí nígbà gbogbo, ní ìgbà ìpọ́njú. Nítorí náà ẹ̀rù kò ní bà wá bí ayé tilẹ̀ ṣídìí, bí àwọn òkè ńlá tilẹ̀ ṣípò pada, tí wọ́n bọ́ sinu òkun

Verse Images for ORIN DAFIDI 46:1-2

ORIN DAFIDI 46:1-2 - Ọlọrun ni ààbò ati agbára wa,
olùrànlọ́wọ́ tí ó wà nítòsí nígbà gbogbo, ní ìgbà ìpọ́njú.
Nítorí náà ẹ̀rù kò ní bà wá bí ayé tilẹ̀ ṣídìí,
bí àwọn òkè ńlá tilẹ̀ ṣípò pada, tí wọ́n bọ́ sinu òkunORIN DAFIDI 46:1-2 - Ọlọrun ni ààbò ati agbára wa,
olùrànlọ́wọ́ tí ó wà nítòsí nígbà gbogbo, ní ìgbà ìpọ́njú.
Nítorí náà ẹ̀rù kò ní bà wá bí ayé tilẹ̀ ṣídìí,
bí àwọn òkè ńlá tilẹ̀ ṣípò pada, tí wọ́n bọ́ sinu òkun

Free Reading Plans and Devotionals related to ORIN DAFIDI 46:1-2