YouVersion Logo
Search Icon

ÌWÉ ÒWE 30:8

ÌWÉ ÒWE 30:8 YCE

Jẹ́ kí ìwà èké ati irọ́ pípa jìnnà sí mi, má jẹ́ kí n talaka, má sì jẹ́ kí n di ọlọ́rọ̀, fún mi ní ìwọ̀nba oúnjẹ tí ó tó mi jẹ