YouVersion Logo
Search Icon

ÌWÉ ÒWE 10:3

ÌWÉ ÒWE 10:3 YCE

OLUWA kì í jẹ́ kí ebi pa olódodo, ṣugbọn ó máa ń da ìfẹ́ ọkàn eniyan burúkú rú.

Free Reading Plans and Devotionals related to ÌWÉ ÒWE 10:3