YouVersion Logo
Search Icon

EFESU 4:26-27

EFESU 4:26-27 YCE

Bí ẹ bá bínú, ẹ má jẹ́ kí ibinu mu yín dẹ́ṣẹ̀. Ẹ má ṣe jẹ́ kí oòrùn wọ̀ ba yín ninu ibinu. Ẹ má fi ààyè gba Èṣù.

Free Reading Plans and Devotionals related to EFESU 4:26-27