YouVersion Logo
Search Icon

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 4:9-10

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 4:9-10 YCE

Eniyan meji sàn ju ẹnìkan ṣoṣo lọ, nítorí wọn yóo lè jọ ṣiṣẹ́, èrè wọn yóo sì pọ̀. Bí ọ̀kan bá ṣubú, ekeji yóo gbé e dìde. Ṣugbọn ẹni tí ó dá wà gbé! Nítorí nígbà tí ó bá ṣubú kò ní sí ẹni tí yóo gbé e dìde.

Verse Images for ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 4:9-10

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 4:9-10 - Eniyan meji sàn ju ẹnìkan ṣoṣo lọ,
nítorí wọn yóo lè jọ ṣiṣẹ́,
èrè wọn yóo sì pọ̀.
Bí ọ̀kan bá ṣubú,
ekeji yóo gbé e dìde.
Ṣugbọn ẹni tí ó dá wà gbé!
Nítorí nígbà tí ó bá ṣubú
kò ní sí ẹni tí yóo gbé e dìde.ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 4:9-10 - Eniyan meji sàn ju ẹnìkan ṣoṣo lọ,
nítorí wọn yóo lè jọ ṣiṣẹ́,
èrè wọn yóo sì pọ̀.
Bí ọ̀kan bá ṣubú,
ekeji yóo gbé e dìde.
Ṣugbọn ẹni tí ó dá wà gbé!
Nítorí nígbà tí ó bá ṣubú
kò ní sí ẹni tí yóo gbé e dìde.

Free Reading Plans and Devotionals related to ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 4:9-10