ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 3:2-3
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 3:2-3 YCE
àkókò bíbí wà, àkókò kíkú sì wà; àkókò gbígbìn wà, àkókò kíkórè ohun tí a gbìn sì wà. Àkókò pípa wà, àkókò wíwòsàn sì wà, àkókò wíwó lulẹ̀ wà, àkókò kíkọ́ sì wà.