Bible App logo
Search Icon

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 18:8

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 18:8 YCE

Kirisipu, ẹni tí ń darí ètò ilé ìpàdé àwọn Juu gba Oluwa gbọ́ pẹlu gbogbo ilé rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni pupọ ninu àwọn ará Kọrinti; nígbà tí wọ́n gbọ́ ọ̀rọ̀ Oluwa, wọ́n gbàgbọ́, wọ́n bá ṣe ìrìbọmi.

Free Reading Plans and Devotionals related to ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 18:8