ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 16:34
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 16:34 YCE
Ó bá mú wọn wọ ilé, ó fún wọn ní oúnjẹ. Inú òun ati gbogbo ìdílé rẹ̀ dùn pupọ nítorí ó ti gba Ọlọrun gbọ́.