YouVersion Logo
Search Icon

ÀWỌN ỌBA KEJI 5:1

ÀWỌN ỌBA KEJI 5:1 YCE

Naamani, olórí ogun Siria, jẹ́ eniyan pataki ati ọlọ́lá níwájú ọba Siria, nítorí pé nípasẹ̀ rẹ̀ ni OLUWA ṣe fún ilẹ̀ Siria ní ìṣẹ́gun. Ó jẹ́ akọni jagunjagun, ṣugbọn adẹ́tẹ̀ ni.

Free Reading Plans and Devotionals related to ÀWỌN ỌBA KEJI 5:1