YouVersion Logo
Search Icon

ÀWỌN ỌBA KINNI 9:4-5

ÀWỌN ỌBA KINNI 9:4-5 YCE

Bí o bá sìn mí tọkàntọkàn pẹlu òtítọ́ inú, gẹ́gẹ́ bí Dafidi, baba rẹ, ti ṣe, bí o bá ṣe gbogbo ohun tí mo pa láṣẹ fún ọ, tí o sì pa òfin ati ìlànà mi mọ́, n óo fìdí ìjọba rẹ múlẹ̀ ní Israẹli, gẹ́gẹ́ bí mo ti ṣèlérí fún Dafidi, baba rẹ, pé arọmọdọmọ rẹ̀ ni yóo máa jọba lórí àwọn ọmọ Israẹli títí lae.

Free Reading Plans and Devotionals related to ÀWỌN ỌBA KINNI 9:4-5