YouVersion Logo
Search Icon

ÀWỌN ỌBA KINNI 18:21

ÀWỌN ỌBA KINNI 18:21 YCE

Elija bá súnmọ́ gbogbo àwọn eniyan, ó wí fún wọn pé, “Yóo ti pẹ́ tó, tí ẹ óo fi máa ṣe iyèméjì? Bí ó bá jẹ́ pé OLUWA ni Ọlọrun, ẹ máa sìn ín. Bí ó bá sì jẹ́ pé oriṣa Baali ni ẹ máa bọ ọ́.” Ṣugbọn àwọn eniyan náà kò sọ ohunkohun.

Free Reading Plans and Devotionals related to ÀWỌN ỌBA KINNI 18:21