1
Ẹk. Jer 3:22-23
Bibeli Mimọ
YBCV
Ãnu Oluwa ni, ti awa kò parun tan, nitori irọnu-ãnu rẹ kò li opin. Ọtun ni li orowurọ; titobi ni otitọ rẹ.
Compare
Explore Ẹk. Jer 3:22-23
2
Ẹk. Jer 3:24
Oluwa ni ipin mi, bẹ̃li ọkàn mi wi; nitorina ni emi ṣe reti ninu rẹ̀.
Explore Ẹk. Jer 3:24
3
Ẹk. Jer 3:25
Oluwa ṣe rere fun gbogbo ẹniti o duro dè e, fun ọkàn ti o ṣafẹri rẹ̀.
Explore Ẹk. Jer 3:25
4
Ẹk. Jer 3:40
Jẹ ki a wádi, ki a si dán ọ̀na wa wò, ki a si tun yipada si Oluwa.
Explore Ẹk. Jer 3:40
5
Ẹk. Jer 3:57
Iwọ sunmọ itosi li ọjọ ti emi kigbe pè ọ: iwọ wipe: Má bẹ̀ru!
Explore Ẹk. Jer 3:57
Home
Bible
Plans
Videos