1
Iṣe Apo 15:11
Bibeli Mimọ
YBCV
Ṣugbọn awa gbagbọ́ pe nipa ore-ọfẹ Oluwa Jesu awa ó là, gẹgẹ bi awọn.
Compare
Explore Iṣe Apo 15:11
2
Iṣe Apo 15:8-9
Ati Ọlọrun, ti iṣe olumọ-ọkàn, o jẹ wọn li ẹrí, o nfun wọn li Ẹmí Mimọ́, gẹgẹ bi awa: Kò si fi iyatọ si ãrin awa ati awọn, o nfi igbagbọ́ wẹ̀ wọn li ọkàn mọ́.
Explore Iṣe Apo 15:8-9