1
ORIN DAFIDI 71:5
Yoruba Bible
YCE
Nítorí ìwọ OLUWA, ni ìrètí mi, OLUWA, Ọlọrun mi, ìwọ ni mo gbẹ́kẹ̀lé láti ìgbà èwe mi.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 71:5
2
ORIN DAFIDI 71:3
Máa ṣe àpáta ààbò fún mi, jẹ́ odi alágbára fún mi kí o sì gbà mí, nítorí ìwọ ni ààbò ati odi mi.
Explore ORIN DAFIDI 71:3
3
ORIN DAFIDI 71:14
Ní tèmi, èmi ó máa ní ìrètí nígbà gbogbo, n óo sì túbọ̀ máa yìn ọ́.
Explore ORIN DAFIDI 71:14
4
ORIN DAFIDI 71:1
OLUWA, ìwọ ni mo sá di; má jẹ́ kí ojú ó tì mí laelae!
Explore ORIN DAFIDI 71:1
5
ORIN DAFIDI 71:8
Ẹnu mi kún fún ìyìn rẹ, ó kún fún ògo rẹ tọ̀sán-tòru.
Explore ORIN DAFIDI 71:8
6
ORIN DAFIDI 71:15
N óo máa ṣírò iṣẹ́ rere rẹ, n óo máa ròyìn iṣẹ́ ìgbàlà rẹ tọ̀sán-tòru, nítorí wọ́n pọ̀ tóbẹ́ẹ̀ tí n kò lè mọ iye wọn.
Explore ORIN DAFIDI 71:15