1
ORIN DAFIDI 64:10
Yoruba Bible
YCE
Kí àwọn olódodo máa yọ̀ ninu OLUWA, kí wọ́n sì máa wá ààbò lọ́dọ̀ rẹ̀! Kí gbogbo ẹni pípé máa ṣògo.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 64:10
2
ORIN DAFIDI 64:1
Ọlọrun, gbọ́ ìráhùn mi; pa mí mọ́ lọ́wọ́ ìdẹ́rùbà ọ̀tá
Explore ORIN DAFIDI 64:1