1
ORIN DAFIDI 61:1-2
Yoruba Bible
YCE
Gbọ́ igbe mi, Ọlọrun, fetí sí adura mi. Láti ọ̀nà jíjìn réré ni mo ti ké pè ọ́, nígbà tí àárẹ̀ mú mi.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 61:1-2
2
ORIN DAFIDI 61:3
nítorí ìwọ ni ààbò mi, ìwọ ni ilé ìṣọ́ tí ó lágbára láti dáàbò bò mí lọ́wọ́ ọ̀tá.
Explore ORIN DAFIDI 61:3
3
ORIN DAFIDI 61:4
Jẹ́ kí n máa gbé inú àgọ́ rẹ títí lae, kí n lè máa wà láìléwu lábẹ́ ààbò ìyẹ́ rẹ.
Explore ORIN DAFIDI 61:4