1
ORIN DAFIDI 54:4
Yoruba Bible
YCE
Ṣugbọn Ọlọrun ni olùrànlọ́wọ́ mi, OLUWA ni ó gbé ẹ̀mí mi ró.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 54:4
2
ORIN DAFIDI 54:7
O ti yọ mí ninu gbogbo ìṣòro mi, mo sì ti fi ojú mi rí ìṣubú àwọn ọ̀tá mi.
Explore ORIN DAFIDI 54:7
3
ORIN DAFIDI 54:6
N óo rú ẹbọ ọrẹ àtinúwá sí ọ, n óo máa yin orúkọ rẹ, OLUWA, nítorí pé ó dára bẹ́ẹ̀.
Explore ORIN DAFIDI 54:6
4
ORIN DAFIDI 54:2
Gbọ́ adura mi, Ọlọrun; tẹ́tí sí ọ̀rọ̀ ẹnu mi.
Explore ORIN DAFIDI 54:2