1
ORIN DAFIDI 52:8
Yoruba Bible
YCE
Ṣugbọn èmi dàbí igi olifi tútù tí ń dàgbà ninu ilé OLUWA, mo gbẹ́kẹ̀lé ìfẹ́ Ọlọrun tí kì í yẹ̀, lae ati laelae.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 52:8
2
ORIN DAFIDI 52:9
N óo máa dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ títí lae, nítorí ohun tí o ṣe, n óo máa kéde orúkọ rẹ níwájú àwọn olùfọkànsìn rẹ, nítorí pé ó dára bẹ́ẹ̀.
Explore ORIN DAFIDI 52:9