1
ÌWÉ ÒWE 5:21
Yoruba Bible
YCE
Nítorí OLUWA rí gbogbo ohun tí eniyan ń ṣe, ó sì ń ṣàkíyèsí gbogbo ìrìn rẹ̀.
Compare
Explore ÌWÉ ÒWE 5:21
2
ÌWÉ ÒWE 5:15
Ìwọ ọkọ, láti inú àmù rẹ ni kí o ti máa mu omi; omi tí ń sun láti inú kànga rẹ ni kí o máa mu.
Explore ÌWÉ ÒWE 5:15
3
ÌWÉ ÒWE 5:22
Eniyan burúkú a máa jìn sinu ọ̀fìn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, a sì bọ́ sinu ìyọnu nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.
Explore ÌWÉ ÒWE 5:22
4
ÌWÉ ÒWE 5:3-4
Nítorí ẹnu alágbèrè obinrin a máa dùn bí oyin, ọ̀rọ̀ rẹ̀ sì tuni lára ju òróró lọ, ṣugbọn níkẹyìn ọ̀rọ̀ rẹ̀ á korò bí iwọ, ẹnu rẹ̀ á sì mú bí idà olójú meji.
Explore ÌWÉ ÒWE 5:3-4
Home
Bible
Plans
Videos