1
ÌWÉ ÒWE 31:30
Yoruba Bible
YCE
Ẹ̀tàn ni ojú dáradára, asán sì ni ẹwà, obinrin tí ó bá bẹ̀rù OLUWA ni ó yẹ kí á yìn.
Compare
Explore ÌWÉ ÒWE 31:30
2
ÌWÉ ÒWE 31:25-26
Agbára ati ọlá ni ó fi ń bora bí aṣọ, ó sì ní ìrètí ayọ̀ nípa ọjọ́ iwájú. Ọ̀rọ̀ ọgbọ́n ní ń jáde láti ẹnu rẹ̀, a sì máa kọ́ni ní ẹ̀kọ́ àánú.
Explore ÌWÉ ÒWE 31:25-26
3
ÌWÉ ÒWE 31:20
Ó lawọ́ sí àwọn talaka, a sì máa ran àwọn aláìní lọ́wọ́.
Explore ÌWÉ ÒWE 31:20
4
ÌWÉ ÒWE 31:10
Ta ló lè rí iyawo tí ó ní ìwà rere fẹ́? Ó ṣọ̀wọ́n ju ohun ọ̀ṣọ́ olówó iyebíye lọ.
Explore ÌWÉ ÒWE 31:10
5
ÌWÉ ÒWE 31:31
Fún un ninu èrè iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀, jẹ́ kí wọn máa yìn ín lẹ́nu ibodè nítorí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.
Explore ÌWÉ ÒWE 31:31
6
ÌWÉ ÒWE 31:28
Àwọn ọmọ rẹ̀ a máa pè é ní ẹni ibukun, ọkọ rẹ̀ pẹlu a sì máa yìn ín pé
Explore ÌWÉ ÒWE 31:28
Home
Bible
Plans
Videos