1
ÀWỌN ADÁJỌ́ 4:4
Yoruba Bible
YCE
Wolii obinrin kan, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Debora aya Lapidotu, ni adájọ́ ní ilẹ̀ Israẹli nígbà náà.
Compare
Explore ÀWỌN ADÁJỌ́ 4:4
2
ÀWỌN ADÁJỌ́ 4:9
Debora dáhùn pé, “Láìṣe àní àní, n óo bá ọ lọ. Ṣugbọn ṣá o, ohun tí o fẹ́ ṣe yìí kò ní já sí ògo fún ọ, nítorí pé, OLUWA yóo fi Sisera lé obinrin kan lọ́wọ́.” Debora bá gbéra, ó bá Baraki lọ sí Kedeṣi.
Explore ÀWỌN ADÁJỌ́ 4:9
Home
Bible
Plans
Videos