1
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 23:11
Yoruba Bible
YCE
Ní òru ọjọ́ keji, Oluwa dúró lẹ́bàá Paulu, ó ní, “Ṣe ọkàn rẹ gírí. Gẹ́gẹ́ bí o ti jẹ́rìí iṣẹ́ mi ní Jerusalẹmu, bẹ́ẹ̀ ni o níláti jẹ́rìí nípa mi ní Romu náà.”
Compare
Explore ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 23:11
Home
Bible
Plans
Videos