1
ÀWỌN ỌBA KINNI 22:22
Yoruba Bible
YCE
OLUWA bá bi í pé, ‘Ọgbọ́n wo ni o óo dá?’ Ẹ̀mí náà dáhùn pé, ‘N óo mú kí gbogbo àwọn wolii Ahabu purọ́ fún un.’ OLUWA bá dáhùn pé, ‘Lọ tàn án jẹ, o óo ṣe àṣeyọrí.’
Compare
Explore ÀWỌN ỌBA KINNI 22:22
2
ÀWỌN ỌBA KINNI 22:23
“Nítorí náà, gbọ́ nisinsinyii, OLUWA ni ó jẹ́ kí àwọn wolii wọnyi máa purọ́ fún ọ, nítorí pé ó ti pinnu láti jẹ́ kí ibi bá ọ.”
Explore ÀWỌN ỌBA KINNI 22:23
3
ÀWỌN ỌBA KINNI 22:21
Ẹ̀mí kan bá jáde siwaju OLUWA, ó ní, ‘N óo lọ tàn án jẹ.’
Explore ÀWỌN ỌBA KINNI 22:21
4
ÀWỌN ỌBA KINNI 22:20
OLUWA bèèrè pé, ‘Ta ni yóo lọ tan Ahabu jẹ, kí ó lè lọ sí Ramoti Gileadi kí wọ́n sì pa á níbẹ̀?’ Bí angẹli kan ti ń sọ ọ̀kan bẹ́ẹ̀ ni òmíràn sì ń sọ nǹkan mìíràn.
Explore ÀWỌN ỌBA KINNI 22:20
5
ÀWỌN ỌBA KINNI 22:7
Ṣugbọn Jehoṣafati bèèrè pé, “Ṣé kò tún sí wolii OLUWA mìíràn mọ́, tí a lè wádìí lọ́dọ̀ rẹ̀?”
Explore ÀWỌN ỌBA KINNI 22:7