Gẹnẹsisi 37:6-7

Gẹnẹsisi 37:6-7 BMYO

O wí fún wọn pé, “Ẹ fetí sí àlá tí mo lá, sá à wò ó, àwa ń yí ìtí ọkà nínú oko, ó sì ṣe ìtí ọkà tèmi sì dìde dúró ṣánṣán, àwọn ìtí ọkà tiyín sì dúró yí ìtí tèmi ká, wọ́n sì ń foríbalẹ̀ fún un.”

Video vir Gẹnẹsisi 37:6-7