Kristi Imole t‘o da wa sileÀpẹrẹ

Ni ìgboyà Ninu Kristi
Ọlọrun onkuna akoko ti obá farabalẹ dúró dē. Ipá wa láti dúró dē amã fi ìgboyà rẹ nínú Ọlọrun hañ.
Kọkọrọ Ẹkọ tó ṣe pàtàkì ni yii; máṣe fi ayé silẹ fún ẹrú tàbi irẹwẹsi ọkan tó lè mú kí o gbe ìgbésẹ ipaiyá tabi ṣe ìpinnu oniwàdu-wádu. Ṣe ìpinnu láti dúró dē Ọlọrun ni ibí ijiroro nínú ọrọ ọlọrun, ìjọsìn ni iwaju rẹ àti Adura titi ti imọlẹ rẹ yóò ṣẹ yọ.
Kíyèsi ìdánilójú ọrọ ọlọrun tõni; ti obá dúró dē pẹlu igboya, Olùwà yíò fún ọkàn rẹ ni okun - ãrẹ ọkan ki yóò bóri rẹ. (ẹsẹ 14)
Iwọ yóò rí iré Oluwa ni ilẹ alãye.
Oluwa rán mi lọwọ láti dúró dē Ọ ni ibí ìjọsìn, adura ati ijiroro nínú ọrọ Rẹ.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Fun gbogbo àkókò òkunkun - ibẹrubojo ati sáà ìyè meji, àkò le ṣe alaimanilo imọlẹ gidgidi ni oniruru ọna. Láti fún wa ní Òye nípa ipò tí a wá tabi ọgbọn fún ìyípadà ilakọja ti ko dára fún réré. Eleyi ni jesu wá sí ayé láti musẹ. O sọ nínú ọrọ iṣẹ rẹ wípé "Emi ni imọlẹ aiye; ẹniti o ba tọ mi lẹhin kì yio rìn ninu òkunkun Johanu 8:12.
More
A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Adeoye Gideon fún pípèsè ètò yìí. Fún ìsọfúnni síwájú sí i, jọ̀wọ́ lọ sí: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL