Kristi Imole t‘o da wa sileÀpẹrẹ

Ma Dẹkun Wiwà Rẹ
Ọkàn ninu awọn akitiyan to ṣe pàtàkì fún ọ gẹgẹ bí onigbagbọ nínú Kristi ni lati dúró nínú Ìfẹ Rẹ.
Ọta nì yíò ṣe ohungbogbo lati yā ọ nipa pẹlu Kristi.
Ninu Johanu 15:7 Jesu wipe;
"Bi ẹnyin ba ngbé inu mi, ti ọ̀rọ mi ba si ngbé inu nyin, ẹ ó bère ohunkohun ti ẹ ba fẹ, a o si ṣe e fun nyin".
Dandan ni pé ō bisi nínú Ìṣẹgun, ayọ àti àlàáfíà ti oba wa nínú irẹpọ pẹlu Ọlọrun. Maṣe dé ikorita ti omā l'ero ati dẹkun Wiwà Ọlọrun. Ọlọrun ní ohungbogbo ti o nilo ohungbogbo ti osi nilo ni Ọlọrun.
Óluwa ràn mí lọwọ láti má dẹ́kun wíwá Ọ.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Fun gbogbo àkókò òkunkun - ibẹrubojo ati sáà ìyè meji, àkò le ṣe alaimanilo imọlẹ gidgidi ni oniruru ọna. Láti fún wa ní Òye nípa ipò tí a wá tabi ọgbọn fún ìyípadà ilakọja ti ko dára fún réré. Eleyi ni jesu wá sí ayé láti musẹ. O sọ nínú ọrọ iṣẹ rẹ wípé "Emi ni imọlẹ aiye; ẹniti o ba tọ mi lẹhin kì yio rìn ninu òkunkun Johanu 8:12.
More
A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Adeoye Gideon fún pípèsè ètò yìí. Fún ìsọfúnni síwájú sí i, jọ̀wọ́ lọ sí: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL